🔍

Olodumare lyrics

Atabatubu Olodumare Oba mimo
Oba mi olola
Oba mi ologo
Oba imole
Kabiyesi Olodumare
Eni to d’aye at’orun
To dami laworan re
Abiyamo ode orun
Atabatubu Olodumare Oba pipe
Oba to momi, Oba to moomi
Omi imi e simi
Sebi iwo lo ni kin maa mi
Lo ni kin maa yo
Lo ni kin maa yonfanda o
Ninu ogo gangan lo tin fohun
Ninu ola nlanla lo tin sise
Ah n o yin o logo
N o se o loba
N o sa ferire re
Oba mi olola
Oba mi olola
Ti Baba lase o, ti Baba loye
Ti Baba lase o, ti Baba loye
Ni ghohungbohun oro re
Emi mimo bale mi
Ara mi si ya gaga
Ti Baba lase
I lean on
Oro ti n gbenu omo eda sise
On your word
Eyi ti n gbenu omo eda d’ogo
On your word oh God
Olodumare, Oba akoda, Oba aseda
On your word oh God
T’o ba ti n s’oro be naa ni o
Ti Baba lase o, ti Baba loye (I lean on)
Ti Baba lase o, ti Baba loye (On your word)
Ni gbohungbohun oro re (On your word oh God)
Emi mimo bale mi
Ara mi si ya gaga (On your word oh God)
Ti Baba lase
Oremi atata
Baba Alailenikan
Eni to femi o
K’aye to momi